| Nelson Rolihlahla Mandela je Aare Guusu Afrika lati 1994 di 1999, beesini ohun ni Aare Guusu Afrika akoko to je didiboyan ninu idiboyan toseluarailu asoju yanyan. |
Nelson Rolihlahla Mandela was the president of South Africa from 1994 to 1999. |
| Ki oto di aare, Mandela je alakitiyan olodi-apartheid, ati olori Umkhonto we Sizwe, apa adigun Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC). |
Before becoming president, Mandela was an anti-apartheid activist, and leader of Umkhonto we Sizwe, the main wing of the African National Congress (ANC). |
| Ni 1962 o je fifofinmu o si je didalebi ika ote ati awon esun miran, o si je riran si ewon fun lailai. |
In 1962, he was accused of murder and was convicted of fraud and other charges, and was sent to prison for life. |
| Mandela lo odun 27 ni ewon, o lo opo odun yi ni Robben Island. |
Mandela spent 27 years in prison, he spent most of this year in Robben Island. |
| Leyin ijowo re kuro logba ewon ni ojo 11 Osu Keji 1990, Mandela lewaju egbe oloselu re ninu awon iforojomitorooro to fa oseluarailu gbogbo eya waye ni 1994. |
After his release from prison on the 11th of February 1990, Mandela was at the forefront of his political party in the 1994 protests that led to an all-ethnic uprising. |
| Gege bi aare lati 1994 de 1999, o sise fun ifowosowopo. |
As president from 1994 to 1999, he worked for cooperation. |
| Ni Guusu Afrika, Mandela tun je mimo bi Madiba, oye eye ti awon alagba idile Mandela unlo. |
In South Africa, Mandela is also known as Madiba, the spiritual leader of the elders of the Mandela family |
| Mandela ti gba ebun topo ju 250 lo ni arin ogoji odun, ninu won ni Ebun Nobel Alafia 1993. |
Mandela has received more than 250 awards in the middle of forty years, among them the Nobel Peace Prize in 1993. |